Lucid cover

Happy People Paroles

Aṣa

Album Lucid

Paroles de Happy People

O òré mi Láídé
Níbo ló dà l'ójó Saturday yìí
Hmmm... Wón se party níhìn o
L'Ókè súnáà léhìn kùlé àwon Làtí

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Oh we're happy people
And that's who we are
We're having fun
We're the children of the sun

Oh we're happy people
And that's who we are
We don't care
We're the children of the sun

O òré mi Laide Ànkárá la dá
Kòstúmù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Ànkárá la dá
Gèlè búlúù la wò
Kosé l'afi gbóyàn sókè
Bàtà mí ti ready

Oh we're happy people
And that's who we are
We're having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that's who we are
We don't care
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that's who we are
We're having fun
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that's who we are
Oh we don't care
We are the children of the sun

Oh oh we happy people
And that's who we are now
Oh we don't care
We are the children of the sun