Home
Top Artistes
Top Paroles
Ajouter Paroles
Contact
menu
search
Contactez-nous
Artiste:
Asake
Titre:
Olorun
Assurez-vous que les corrections sont tout à fait exactes
S'il vous plaît, les mettez en évidence en quelque sorte!
Vous pouvez, par exemple, écrire
INCORRECT: avant la mauvaise ligne
CORRECT: avant la correspondant ligne correcte
Autrement, nous ne pouvons les corriger pas! Merci pour votre aide.
Ololade mi asake Emi kọ ọlọrun ma ni Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Emi kọ oọlọrun ma ni Ta lo gbọn t'olorun (Ọmọ ọgbọn) Kosi anybody to lo gbon t'olorun Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ Wọn ti sapa mọ Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Ọmọ no be me shebi na God Carry me from down straight to the top 2020 it was real tough Fall for ground almost gave up Mo fun won lo ọmọ ọpe mo de je lo Go naked in my room and speak to God Baba god I no sabi all So guide me as I dey move on on on Ta lo gbọn t'olorun Kosi anybody to lo gbon t'olorun Ti wọn ba buga ẹ oya gba fun olorun Awọn ti wọn buga mi wọn ti sapa mọ Wọn ti sapa mọ Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Emi kọ ọlọrun ma ni (Ọlọrun ma ni) Emi kọ o ọlọrun ma ni Awa kọ oh oh Ọlọrun ma ni (Oh oh oh) Emi kọ ọlọrun ma ni Nkan kan o gbọdọ se awọn ọmọ ologo o Mimi kan o gbọdọ mi awọn ọmọ ọlọrun o Alhamdulillah I’m a brand new man Tune in to the king of sounds and blues